Yorùbá Bibeli

Joṣ 9:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe li opin ijọ́ mẹta, lẹhin ìgbati nwọn bá wọn dá majẹmu, ni nwọn gbọ́ pe aladugbo wọn ni nwọn, ati pe làrin wọn ni nwọn gbé wà.

Joṣ 9

Joṣ 9:7-24