Yorùbá Bibeli

Joṣ 9:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joṣua si bá wọn ṣọrẹ, o si bá wọn dá majẹmu lati da wọn si: awọn olori ijọ enia fi OLUWA Ọlọrun Israeli bura fun wọn.

Joṣ 9

Joṣ 9:8-20