Yorùbá Bibeli

Joṣ 24:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ẹnyin ba kọ̀ OLUWA silẹ, ti ẹ ba si sìn ọlọrun ajeji, nigbana ni on o pada yio si ṣe nyin ni ibi, yio si run nyin, lẹhin ti o ti ṣe nyin li ore tán.

Joṣ 24

Joṣ 24:16-28