Yorùbá Bibeli

Joṣ 16:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Àla na si lọ si ìha ìwọ-õrùn si ìha ariwa Mikmeta; àla na si yi lọ si ìha ìla-õrùn dé Taanati-ṣilo, o si kọja lẹba rẹ̀ lọ ni ìha ìla-õrùn Janoha;

Joṣ 16

Joṣ 16:2-8