Yorùbá Bibeli

Joṣ 12:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose iranṣẹ OLUWA ati awọn ọmọ Israeli kọlù wọn: Mose iranṣẹ OLUWA si fi i fun awọn ọmọ Reubeni ni ilẹ-iní, ati fun awọn ọmọ Gadi, ati fun àbọ ẹ̀ya Manasse.

Joṣ 12

Joṣ 12:3-12