Yorùbá Bibeli

Joṣ 12:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si jọba li òke Hermoni, ati ni Saleka, ati ni gbogbo Baṣani, titi o fi dé àgbegbe awọn Geṣuri ati awọn Maakati, ati àbọ Gileadi, àla Sihoni ọba Heṣboni.

Joṣ 12

Joṣ 12:3-9