Yorùbá Bibeli

3. Joh 1:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Demetriu li ẹri rere lọdọ gbogbo enia ati ti otitọ tikararẹ̀ pẹlu: nitõtọ, awa pẹlu si gbà ẹrí rẹ̀ jẹ; ẹnyin si mọ̀ pe otitọ ni ẹrí wa.

3. Joh 1

3. Joh 1:9-15