Yorùbá Bibeli

2. Tim 4:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Oluwa gbà ẹjọ mi ro, o si fun mi lagbara; pe nipasẹ mi ki a le wãsu na ni awàjálẹ̀, ati pe ki gbogbo awọn Keferi ki o le gbọ́: a si gbà mi kuro li ẹnu kiniun nì.

2. Tim 4

2. Tim 4:10-22