Yorùbá Bibeli

2. Tim 4:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li àtetekọ jẹ ẹjọ mi, kò si ẹniti o bá mi gba ẹjọ ro, ṣugbọn gbogbo enia li o kọ̀ mi silẹ: adura mi ni ki a máṣe kà a si wọn li ọrùn.

2. Tim 4

2. Tim 4:12-21