Yorùbá Bibeli

2. Tim 3:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ gẹgẹ bi Janesi ati Jamberi ti kọ oju ija si Mose, bẹ̃li awọn wọnyi kọ oju ija si otitọ: awọn enia ti inu wọn dibajẹ, awọn ẹni ìtanù niti ọran igbagbọ́.

2. Tim 3

2. Tim 3:5-10