Yorùbá Bibeli

2. Sam 7:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati gẹgẹ bi akoko igba ti emi ti fi aṣẹ fun awọn onidajọ lori awọn enia mi, ani Israeli, emi fi isimi fun ọ lọwọ gbogbo awọn ọta rẹ. Oluwa si wi fun ọ pe, Oluwa yio kọ ile kan fun ọ.

2. Sam 7

2. Sam 7:7-17