Yorùbá Bibeli

2. Sam 7:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si yàn ibi kan fun awọn enia mi, ani Israeli, emi o si gbìn wọn, nwọn o si ma joko ni ibujoko ti wọn, nwọn kì yio si ṣipo pada mọ; awọn ọmọ enia buburu kì yio si pọn wọn loju mọ, bi igba atijọ.

2. Sam 7

2. Sam 7:4-18