Yorùbá Bibeli

2. Sam 6:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si pin fun gbogbo awọn enia na, ani fun gbogbo ọpọ enia Israeli, ati ọkunrin ati obinrin; fun olukuluku iṣu akara kan ati ẹkirí ẹran kan, ati akara didun kan. Gbogbo awọn enia na si tuka lọ, olukuluku si ile rẹ̀.

2. Sam 6

2. Sam 6:9-23