Yorùbá Bibeli

2. Sam 5:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo agba Israeli si tọ ọba wá ni Hebroni, Dafidi ọba si ba wọn ṣe adehun kan ni Hebroni, niwaju Oluwa: nwọn si fi ororo yan Dafidi li ọba Israeli.

2. Sam 5

2. Sam 5:1-7