Yorùbá Bibeli

2. Sam 5:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati nigba atijọ, nigbati Saulu fi jọba lori wa, iwọ ni ẹniti ima ko Israeli jade, iwọ ni si ma mu wọn bọ̀ wá ile: Oluwa si wi fun ọ pe, Iwọ o bọ́ Israeli awọn enia mi, iwọ o si jẹ olori fun Israeli.

2. Sam 5

2. Sam 5:1-9