Yorùbá Bibeli

2. Sam 3:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si wi pe, O dara, emi o ba ọ ṣe adehun: ṣugbọn nkan kan li emi o bere lọwọ rẹ, eyini ni, Iwọ ki yio ri oju mi, afi bi iwọ ba mu Mikali ọmọbinrin Saulu wá, nigbati iwọ ba mbọ, lati ri oju mi.

2. Sam 3

2. Sam 3:11-20