Yorùbá Bibeli

2. Sam 3:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Abneri si ran awọn oniṣẹ si Dafidi nitori rẹ̀, wipe, Ti tani ilẹ na iṣe? ati pe, Ba mi ṣe adehun, si wõ, ọwọ́ mi o wà pẹlu rẹ, lati yi gbogbo Israeli sọdọ rẹ.

2. Sam 3

2. Sam 3:11-17