Yorùbá Bibeli

2. Sam 2:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joabu si wipe, Bi Ọlọrun ti mbẹ, bikoṣe bi iwọ ti wi, nitotọ, li owurọ̀ li awọn enia na iba ti goke lọ, olukuluku iba ti pada lẹhin arakunrin rẹ̀.

2. Sam 2

2. Sam 2:26-32