Yorùbá Bibeli

2. Sam 2:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Abneri si pe Joabu, o si bi i lere pe, Idà yio ma parun titi lailai bi? njẹ iwọ kò iti mọ̀ pe yio koro nikẹhin? njẹ yio ha ti pẹ to ki iwọ ki o to sọ fun awọn enia na, ki nwọn ki o dẹkun lati ma lepa ará wọn?

2. Sam 2

2. Sam 2:24-32