Yorùbá Bibeli

2. Sam 2:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Seruia mẹtẹta si mbẹ nibẹ, Joabu, Abiṣai, ati Asaheli: ẹsẹ Asaheli si fẹrẹ bi ẹsẹ agbọnrin ti o wà ni pápa.

2. Sam 2

2. Sam 2:11-22