Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 8:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni Joramu rekọja siha Sairi, ati gbogbo awọn kẹkẹ́ pẹlu rẹ̀: o si dide li oru, o si kọlù awọn ara Edomu ti o yi i ka: ati awọn olori awọn kẹkẹ́: awọn enia si sá wọ inu agọ wọn.

2. A. Ọba 8

2. A. Ọba 8:15-23