Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 8:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃li o lọ kuro lọdọ Eliṣa, o si de ọdọ oluwa rẹ̀; on si wi fun u pe, Kini Eliṣa sọ fun ọ? On si dahùn wipe, O sọ fun mi pe, Iwọ o sàn nitõtọ.

2. A. Ọba 8

2. A. Ọba 8:8-22