Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 8:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Hasaeli si wipe, Ṣugbọn kinla? Iranṣẹ rẹ iṣe aja, ti yio fi ṣe nkan nla yi? Eliṣa si dahùn wipe, Oluwa ti fi hàn mi pe, iwọ o jọba lori Siria.

2. A. Ọba 8

2. A. Ọba 8:10-15