Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 7:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ni nwọn dide, nwọn si salọ ni afẹ̀mọjumọ, nwọn si fi agọ wọn silẹ, ati ẹṣin wọn, ati kẹtẹkẹtẹ wọn, ani, ibùdo wọn gẹgẹ bi o ti wà, nwọn si salọ fun ẹmi wọn.

2. A. Ọba 7

2. A. Ọba 7:4-9