Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 6:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni o wipe, Ki Ọlọrun ki o ṣe bayi ati jù bẹ̃ lọ si mi, bi ori Eliṣa ọmọ Ṣafati yio duro li ọrùn rẹ̀ li oni.

2. A. Ọba 6

2. A. Ọba 6:24-33