Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 6:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati ọba gbọ́ ọ̀rọ obinrin na, o fà aṣọ rẹ̀ ya; o si kọja lọ lori odi, awọn enia si wò, si kiyesi i, o ni aṣọ-ọfọ̀ labẹ aṣọ rẹ̀ li ara rẹ̀.

2. A. Ọba 6

2. A. Ọba 6:20-31