Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 6:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si pèse ọ̀pọlọpọ onjẹ fun wọn; nigbati nwọn si ti jẹ, ti nwọn si ti mu tan, o rán wọn lọ, nwọn si tọ̀ oluwa wọn lọ. Bẹ̃ni ẹgbẹ́ ogun Siria kò tun wá si ilẹ Israeli mọ.

2. A. Ọba 6

2. A. Ọba 6:16-24