Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 6:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si dahùn pe, Iwọ kò gbọdọ pa wọn: iwọ jẹ pa awọn ti iwọ fi idà rẹ ati ọrun rẹ kó ni igbèkun? Gbe onjẹ ati omi kalẹ niwaju wọn, ki nwọn ki o jẹ, ki nwọn ki o si mu, ki nwọn ki o si tọ̀ oluwa wọn lọ.

2. A. Ọba 6

2. A. Ọba 6:16-25