Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 6:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati nwọn de Samaria ni Eliṣa wipe, Oluwa la oju awọn enia wọnyi, ki nwọn ki o lè riran. Oluwa si là oju wọn; nwọn si riran; si kiyesi i, nwọn mbẹ li ãrin Samaria.

2. A. Ọba 6

2. A. Ọba 6:11-23