Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 6:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eliṣa si wi fun wọn pe, Eyi kì iṣe ọ̀na, bẹ̃ni eyi kì iṣe ilu na: ẹ ma tọ̀ mi lẹhin, emi o si mu nyin wá ọdọ ọkunrin ti ẹnyin nwá. O si ṣe amọ̀na wọn lọ si Samaria.

2. A. Ọba 6

2. A. Ọba 6:18-27