Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 6:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jẹ ki awa ki o lọ, awa bẹ̀ ọ, si Jordani, ki olukulùku wa ki o mu iti igi kọ̃kan wá, si jẹ ki awa ki o ṣe ibikan, ti awa o ma gbe. On si dahùn wipe, Ẹ mã lọ.

2. A. Ọba 6

2. A. Ọba 6:1-11