Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 6:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba Israeli si ranṣẹ si ibẹ na ti enia Ọlọrun ti sọ fun u, ti o si ti kilọ fun u, o si gbà ara rẹ̀ nibẹ, kì iṣe nigbà kan tabi nigba meji.

2. A. Ọba 6

2. A. Ọba 6:2-16