Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 5:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn on wọ̀ inu ile lọ, o si duro niwaju oluwa rẹ̀. Eliṣa si wi fun u pe, Gehasi, nibo ni iwọ ti mbọ̀? On si wipe, Iranṣẹ rẹ kò lọ ibikibi.

2. A. Ọba 5

2. A. Ọba 5:23-27