Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 5:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Naamani si wipe, Fi ara balẹ, gbà talenti meji. O si rọ̀ ọ, o si dì talenti fadakà meji sinu apò meji, pẹlu ipàrọ aṣọ meji, o si gbé wọn rù ọmọ-ọdọ rẹ̀ meji; nwọn si rù wọn niwaju rẹ̀.

2. A. Ọba 5

2. A. Ọba 5:21-27