Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si di ọjọ kan, Eliṣa si kọja si Ṣunemu, nibiti obinrin ọlọla kan wà; on si rọ̀ ọ lati jẹ onjẹ. O si ṣe, nigbakugba ti o ba nkọja lọ, on a yà si ibẹ lati jẹ onjẹ.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:2-9