Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li o wá, o si sọ fun enia Ọlọrun na. On si wipe, Lọ, tà ororo na, ki o si san gbèse rẹ, ki iwọ ati awọn ọmọ rẹ ki o si jẹ eyi ti o kù.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:1-12