Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:43 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iranṣẹ rẹ̀ si wipe, Kinla, ki emi ki o gbé eyi kà iwaju ọgọrun enia? On si tun wipe, Fi fun awọn enia, ki nwọn ki o le jẹ: nitori bayi li Oluwa wi pe, Nwọn o jẹ, nwọn o si kù silẹ.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:35-44