Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọkunrin kan si ti Baali-Ṣaliṣa wá, o si mu àkara akọso-eso, ogun iṣu àkara barle, ati ṣiri ọkà titun ninu àpo rẹ̀ wá fun enia Ọlọrun na. On si wipe, Fi fun awọn enia, ki nwọn ki o le jẹ.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:38-44