Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eliṣa si wi fun u pe, Kini emi o ṣe fun ọ? Wi fun mi, kini iwọ ni ninu ile? On si wipe, Iranṣẹbinrin rẹ kò ni nkankan ni ile, bikòṣe ikòko ororo kan.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:1-8