Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 4:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

OBIRIN kan ninu awọn obinrin ọmọ awọn woli ke ba Eliṣa wipe, Iranṣẹ rẹ, ọkọ mi kú; iwọ si mọ̀ pe iranṣẹ rẹ bẹ̀ru Oluwa: awọn onigbèse si wá lati mu awọn ọmọ mi mejeji li ẹrú.

2. A. Ọba 4

2. A. Ọba 4:1-4