Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 25:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gedaliah si bura fun wọn, ati fun awọn ọkunrin wọn, o si wi fun wọn pe, Ẹ má bẹ̀ru lati sìn awọn ara Kaldea: ẹ mã gbe ilẹ na, ki ẹ si mã sìn ọba Babeli; yio si dara fun nyin.

2. A. Ọba 25

2. A. Ọba 25:19-30