Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 25:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati awọn enia ti o kù ni ilẹ Juda, ti Nebukadnessari ọba Babeli fi silẹ, ani, o fi Gedaliah ọmọ Ahikamu, ọmọ Ṣafani, jẹ bãlẹ wọn.

2. A. Ọba 25

2. A. Ọba 25:21-30