Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 25:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba Babeli si kọlù wọn, o si pa wọn ni Ribla ni ilẹ Hamati. Bẹ̃li a mu Juda kuro ni ilẹ rẹ̀.

2. A. Ọba 25

2. A. Ọba 25:18-24