Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 25:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ikòko wọnni, ati ọkọ wọnni, ati alumagàji fitila wọnni, ati ṣibi wọnni, ati gbogbo ohun-èlo wọnni ti nwọn fi nṣiṣẹ, ni nwọn kó lọ.

2. A. Ọba 25

2. A. Ọba 25:4-16