Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 24:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹni ọdun mọkanlelogun ni Sedekiah nigbati o bẹ̀rẹ si ijọba, o si jọba li ọdun mọkanla ni Jerusalemu. Orukọ iya rẹ̀ ni Hamutali, ọmọbinrin Jeremiah ti Libna.

2. A. Ọba 24

2. A. Ọba 24:15-20