Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 23:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati pẹpẹ wọnni ti mbẹ lori iyara òke Ahasi, ti awọn ọba Juda ti tẹ́, ati pẹpẹ wọnni ti Manasse ti tẹ́ li ãfin mejeji ile Oluwa ni ọba wó lulẹ, o si yara lati ibẹ, o si da ekuru wọn sinu odò Kidroni.

2. A. Ọba 23

2. A. Ọba 23:8-21