Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 23:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mu ẹṣin wọnni kuro ti awọn ọba Juda ti fi fun õrun, ni atiwọ̀ inu ile Oluwa lẹba iyẹ̀wu Natan-meleki iwẹ̀fa, ti o ti wà ni agbegbe tempili, o si fi iná sun kẹkẹ́ õrun wọnni.

2. A. Ọba 23

2. A. Ọba 23:9-13