Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 21:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si gbé ere oriṣa fifin kalẹ ti o ti ṣe ni ile na ti Oluwa sọ fun Dafidi ati Solomoni ọmọ rẹ̀ pe, Ni ile yi, ati ni Jerusalemu, ti mo ti yàn ninu gbogbo awọn ẹ̀ya Israeli, li emi o fi orukọ mi si lailai:

2. A. Ọba 21

2. A. Ọba 21:6-14