Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 21:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si mu ki ọmọ rẹ̀ ki o kọja lãrin iná, a si mã ṣe akiyesi afọṣẹ, a si mã ṣe alupàyida, a si mã bá awọn okú ati awọn oṣó lò: o hùwa buburu pupọ̀ li oju Oluwa lati mu u binu.

2. A. Ọba 21

2. A. Ọba 21:1-12