Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 21:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si nà okùn Samaria lori Jerusalemu, ati òjé-idiwọ̀n ile Ahabu: emi o si nù Jerusalemu bi enia ti nnù awokoto, o nnù u, o si ndori rẹ̀ kodò.

2. A. Ọba 21

2. A. Ọba 21:5-18